You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Àkójọpọ̀ èsì ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti
Eyi ni bi awọn esi ibo gomina ṣẹ n jade lati ijọba ibilẹ kọọkan nipinlẹ Ekiti.
Ti o ba ṣe n tẹ ori maapu to wa ni isalẹ, ni abajade esi ibo fun ẹgbẹ oṣelu kọọkan, pẹlu ijọba ibilẹ ti wọn ti bori, yoo maa han si ọ.
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Moba
ADC: 994
APC: 20500
PDP: 1572
SDP: 2
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ekiti East
ADC: 1730
APC: 26359
PDP: 2795
SDP: 65
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Irẹpọdun-Ifẹlodun
ADC: 511
APC: 29278
PDP: 2119
SDP: 2
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ikole
ADC: 812
APC: 26508
PDP: 750
SDP: 13
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ayekire Gbonyin
ADC: 314
APC: 17133
PDP: 1563
SDP:
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ọyẹ
ADC: 998
APC: 18975
PDP: 2891
SDP: 4
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ise Ọrun
ADC: 365
APC: 12908
PDP: 1627
SDP: 7
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ilejemeje
ADC: 579
APC: 8984
PDP: 1243
SDP: 4
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ado Ekiti
ADC: 1054
APC: 38026
PDP: 3817
SDP: 31
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ekiti West
ADC: 674
APC: 28258
PDP: 3644
SDP: 6
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ido Osi
ADC: 561
APC: 17901
PDP: 1449
SDP: 3
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ekiti Southwest
ADC: 1076
APC: 14705
PDP: 1800
SDP: 7
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Emure
ADC: 732
APC: 14325
PDP: 851
SDP: 0
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ikẹrẹ
ADC: 245
APC: 11116
PDP: 9892
SDP:
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Ijero
ADC: 2026
APC: 25506
PDP: 2479
SDP: 29
Esi ibo lati ijọba ibilẹ Efọn
ADC: 201
APC: 8742
PDP: 2051
SDP: 3
Ajọ INEC ti fẹ bẹrẹ kika esi idibo
Gbogbo eto ti to ni Ado Ekiti nibi ti ajọ INEC tí fẹ bẹrẹ si ni maa ka esi idibo ipinlẹ Ekiti tó waye loni.