Irinṣẹ́ òǹkà ọdún ti wà láti ka iye ọdún tó leè lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé, iye ọdún tó ṣeé ṣe kí gbogbo ènìyàn lò láyé, ti fi ọdún méje pọ̀ si láti ọdún 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà ọdún yìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀, ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè to ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Skip Móríwú and continue reading

Móríwú

  • Adeleke
  • Eegun ti awọn eeyan to tẹle lẹyin
  • Shodey wọ asọ toke tilẹ dudu, o lo awo oju, o si ta irun rẹ ni koko
  • Awọn ti wọn padanu eeyan wọn ninu ikọlu ṣọọṣi Ọwọ
  • Eeyan kan ori ibusun rẹ lalẹ
  • Aworan Erelu Funmilayọ ọmọ Elemure Ogunyẹmi
  • Aworan iwọde ni Oyo
  • Aworan bi omi okun se ru titi de odidi ile kan ni Ayetoro
  • Agolo ohun mimu Energy Drink kan
  • Yara ikawe ti iji ojo lile si lọ
  • Erekusu Ẹ̀bá to wa lẹb omi nla

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ